Ọlánrewájú [Album]
Igba o lọ bi orere
Bo ba koro oṣi maa dun ah
Eni to ni suuru kin ṣeyan kekere
Bo ba kan lẹ oṣi maa goke ah
Boo ba ṣe un tọ fe won maa kẹyin si e ẹh a ẹh
Bo ba ṣe tirẹ o o ma jẹ ire fun ẹ ẹh a ẹh
Ọlanrewaju ọmọ Oba
E ma suure da gba o
Won ni ko o ṣe were roora ṣe
E ma suure da gba oo
Olooto ko ni ku si bi ọdẹ ooo
Olanrewaju ọmọ mi e ma suure da gba oo
Igba o lọ bi orere ah ah
Bọmọde oku o o oṣi maa da gba ah ah
Ṣọra funja ṣọ ra fẹgbẹfẹgbẹ ah ah
Oun tio to o oṣi maa pọ da nu ah ah
Gbogbo eni abi lo ma ku eh
Eh a ẹh
Iwa ta a wu lo ma ku ẹh a ẹh
Ọlanrewaju ọmọ Oba e ma suure da gba o
Won ni ko ṣe were roora ṣe
E ma suure da gba oo
Olooto ko ni ku sibi ọtẹ oo
Ọlanrewaju ọmọ mi e ma suure da gba o
Olooto ko ni ku sipo ika oo
Olooto ko ni ku sibi ote oo ha ha ha ha ha ha ha ha
Ọlanrewaju ọmọ Oba ee ma suure dagba oo
Ọlanrewaju ọmọ mi ee ma suure da gba oo