Adedotun

Brymo

Verse 1
Awon adan fo loke
Wan foka si oju Orun
Wan o ma mo ibi won lo
Eledua lo n shey ike won
Ko keyin si é Oré o
O wun o n wa
O wa ni waju re

Hook
Adedotun.......
Oyindamola mi.......
Ero gbogbo e ba gberin
Adedotun o.............

Verse 2
Awon adan fo loke
Ni igba igba
Won ku oju orun
Won o ma mo iwun wan n je
Eledua lo n sho wan
Lo n bo wan
Ko pamo si é
Oré ooooooo
O wa lo sokoto
O wa lapo Sokoto

Hook
Adedotun.......
Oyindamola mi.......
Ero gbogbo e ba gberin
Adedotun o.............
(X2)

Ko pamo si é
Oré o
Owun o n wa
O wa ni waju re
Ore o........

Curiosità sulla canzone Adedotun di Brymo

Quando è stata rilasciata la canzone “Adedotun” di Brymo?
La canzone Adedotun è stata rilasciata nel 2020, nell’album “Yellow”.

Canzoni più popolari di Brymo

Altri artisti di